ENVIAR LETRAS
Top 100
Lanzamientos de álbumes
Artistas
Comunidade
Francés
Portuguese
Inglés
Corrección Letra
Ibadan
par
Olamide
Regreso
Letra
Bi sekere ba ti dun oo Konga a te le A te le Ijo ma tele Antrans ko gi le o fun mi jaree Lateko de challengi A gba gurumaraji Awole pelu bugati Ankara lori fasasi Idi n be n'ibadan o Oke be n'ibadan o Idi arere idi ayunre Oke sango oke mo po Ema je ko di ja Olosho yapa ni bodija o Pelu sokoto pe n pe Awon omo mi ni mo lete Ema soko fun eye twitter Alomo meta feya speaker Furo rabata fe ya bumber Them say them to buggi down Ibadan ni mo wa o Ibadan ni mo re o Ibadan ni mo wa o Ibadan ni mo re o Be wa deko be ba ni le Ibadan ni mo wa oo Ibadan ni mo wa oo E shoutout si awon omo uni Leed city de badan poly Ebami ki kunle silencer Omo musulumi to fa poli Ero to lo london Ebami ki tayo dekida Tiringbeku teletele Omo ibadan to di n***a Omo woli to n fa taba Basira su sara ko ta ba Omugo fe high ogun lada Won de ni momo re feya fada Qdot fe silekun fe kun O yo tan owa be kun bekun I turn up tan osi seku Ka to fi embivadale le odi seven Ibadan ni mo wa o Ibadan ni mo re o Ibadan ni mo wa o Ibadan ni mo re o Be wa deko be ba ni le Ibadan ni mo wa oo Ibadan ni mo wa oo Ni le oluyole ooo Awon omo lagelu Ujo sokky mo gbe wa o No be skelewu Atana wole pelu sanpeni Ki ni a de temi complaini Pe owo afefe la fi sustaini Ahhen ti naira ba ti tan Mabinu ma ko pounsi jade Ko fun mi lolosho to wo gown Won fun mi lorogbo to ti brown Eyi ko lemaso fun wa Pe oshogbo ti di town Eeeeen we rocking gucci gucci Ajoko sori chair kusin Eran chikin la gbe ah nu jawee Ibadan ni mo wa o Ibadan ni mo re o Ibadan ni mo wa o Ibadan ni mo re o Be wa deko be ba ni le Ibadan ni mo wa oo Ibadan ni mo wa oo Ikorodu lo ga wa ooo O Nana, nananana Ni Ile oluyole Omo a fi ikarahun fo’ko mu Nana nana Sakoyo pami o sha Ani ki mami High flyer ni badan Eleshi money Abiodun Olayinka Gulu gulu lo London Mr Ayodele po money Olojo de Olamide badoo Ibadan ni mo wa o Ibadan ni mo re o Ibadan ni mo wa o Ibadan ni mo re o Be wa deko be ba ni le Ibadan ni mo wa oo
videoclip
Tu nombre será publicado. Deje los campos en blanco para permanecer en el anonimato.
Enviar
Modal title
×
Insertar medios
Video URL?
(YouTube, Vimeo, Instagram, DailyMotion, Soundcloud)
×
Recuérdame
Contraseña perdida
Conectarte
Registrarse