SUBMIT LYRICS
Top 100
Album releases
artists
Community
French
Spanish
Portuguese
Correction Lyrics
Happy People
by
Aṣa
Back
Lyrics
O òré mi Láídé Níbo ló dà l'ójó Saturday yìí Hmmm... Wón se party níhìn o L'Ókè súnáà léhìn kùlé àwon Làtí Ànkárá la dá Kòstúmù la wò Kosé l'afi gbóyàn sókè Bàtà mí ti ready Ànkárá la dá Kòstúmù la wò Kosé l'afi gbóyàn sókè Bàtà mí ti ready Oh we're happy people And that's who we are We're having fun We're the children of the sun Oh we're happy people And that's who we are We don't care We're the children of the sun O òré mi Laide Níbo ló kàn l'ójó Sunday yìí Hmmm... Wón gbéyàwó níhin o L'Ókè pópó légbe ilé àwon Toyeeb Ànkárá la dá Kòstúmù la wò Kosé l'afi gbóyàn sókè Bàtà mí ti ready Ànkárá la dá Gèlè búlúù la wò Kosé l'afi gbóyàn sókè Bàtà mí ti ready Oh we're happy people And that's who we are We're having fun We are the children of the sun Oh oh we happy people And that's who we are We don't care We are the children of the sun Oh oh we happy people And that's who we are We're having fun We are the children of the sun Oh oh we happy people And that's who we are Oh we don't care We are the children of the sun Oh oh we happy people And that's who we are now Oh we don't care We are the children of the sun
music video
Your name will be published. Leave fields blanks to remain anonymous.
Submit
Modal title
×
Insert media
Video URL?
(YouTube, Vimeo, Instagram, DailyMotion, Soundcloud)
×
Remember me
Lost password
Sign in
Register